Tope Alabi – Oluwa O Tobi ( Mp3 download & Lyrics )

Oluwa O Tobi; a track by popular Nigerian gospel minister, Tope Alabi in her album Alagbara which she released in 2012, speaks of the incomparable greatness of God. Listen and download music below.

Mp3 download

DOWNLOAD

Lyrics

Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo
Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun
Pupopupo ni O, O koja omi okun at’osa, O ga po
Ajulo O o se julo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oba lori aye, O tobi o eh
Agba’ni loko eru, Olominira to n de’ni lorun
O fi titobi gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka
Olugbeja mi to ba mi r’ogun lai mu mi lo t’o segun
Akoni ni O o
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
B’O ti tobi to oo, laanu Re tobi
B’O ti tobi se o, ododo Re tobi o
O tobi tife tife, Oni majemu ti kii ye
Aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tan
Ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Akoko O tobi, O tobi o
Oluwa
Ipilese ogborin o yeye
O tobi
Ibere Eni to f’ogbon da ohun gbogbo
Oluwa
Igbeyin ola nla, o la la oo
O tobi
Opin aye a’torun ko si ‘ru Re
Oluwa
O tobi, O o se s’akawe lailai o
O tobi
Agbaagba merinlelogun nki O, O tobi
Oluwa
Awon angeli won n ki O, O tobi
O tobi
Olorun Elijah Ireti Ajanaku
Oluwa
O ma tobi laye mi, O tobi ooo
O tobi
Iwo lo gb’orin t’O o ga, t’O gun, t’O tun fe
Oluwa
O ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la la
O tobi

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *